0 0
Read Time:1 Minute, 46 Second

Eyanmi,

Awon agbalagba lo so be ooo. Won ni Odo ti o baa gbagbe orisun re; iru won ma n gbe ni. Oro yi se pataki fun gbogbo wa, paapa awon ti won wa lati idile gidi.

Yoruba 7.jpg

Elomi ti gbagbe ibi ti oti wa. Ti igbega die bati wo inu ile aiye won, won a bere sini tele bashu-bashu bi e ni wipe ko si iru won mo ninu aiye. Igberaga adi ewu ti won wo kiiri. Eni to mu iru iwa bayi lo, koni pe ti isubu won fi ma de.

Ati ri awon ti won gbagbe obi ti o bi won nigbati ara ro won tan. Awon obi won o wa je nkan kan mo lo ju won. Won onifi owo ati ola ti eledumare fi fun won toju awon obi won. Won a maa se yalayolo larin egbe. Karimi ni won a maa ba kaakiri. Iparun ni iru won fin seere oooo.

Igba o lo bi oreere, ore mi. Toju ibi ti oti wa, ko di igba ti a baa lowo bi sekere, iwon ba ti o baa wa ni owo wa ni ise ti o leee se. Ranti ile.

Owo nikan ko lafi hun ranti ile oooo. Gbogbo ipa ti iwo bale ko lati fi gbe ibi toti jade wa laruge, jowo maa shayi she ooo. Je ki gbogbo awon ti o ba wani ayika re mo wipe ibi rere loti jade wa pelu iwa re.

E je ki a ranti ibi ti a tiwa. Ki a ranti gbogbo ore ti Oluwa ti se ninu igbesi aiye wa. Bi a ba ranti orisun wa, ati dupe fun Olorun koni je inira rara.

Ayo wa oni di ibanuje ooo. Amin.

Mo dupe gan fun asiko ti e fisile lati ka aroye mi. E jowo e je kin gbo ero okan yin lori oro yi ni aiye towa ni isale. E dakun e fi ife han mi, Eba mi pin aroye yin fun awon ore yin. Esi ma gbagbe lati darapo mowa ni ibiyi.

Emi ni ti e ni tooto,

Ruka

Check Natural Skincare Products here. Homemade Recipes here.

About Post Author

Ruka

My name is Ruka. Born and bred in Nigeria. Now living in Ireland. I am a Woman, Feminist, Wife, Mother, Muslim, Black, and African. I am an Entrepreneur who also works in Finance Administration. I am a Fibromyalgia & Chronic Pain Warrior. I love writing and hope to make a name for myself doing it.
Happy
Happy
0 %
Sad
Sad
0 %
Excited
Excited
0 %
Sleepy
Sleepy
0 %
Angry
Angry
0 %
Surprise
Surprise
0 %

Average Rating

5 Star
0%
4 Star
0%
3 Star
0%
2 Star
0%
1 Star
0%

3 thoughts on “Odo To Ba Gbagbe Orisun Re…..

  1. Asiri nla ni eleyi fun gbogbo omo luabi tabi ni ile rere, ki a mase gbagbe orisun wa.
    O se ore mi. Adura mi ni wipe ki Eledua ki o ran wa lowo, ki a ma sise. Ki a si ko ere oko dele ni agbara Olorun, amin

Leave a Reply