0 0
Read Time:1 Minute, 32 Second

Eyanmi,

Emi ni igbaagbo pe kadara o le ye. Iwo nko?

Awa Yoruba ni ‘Bi won gun iyan ninu ewe, bi won se obe ninu epo epa, eni ma yo, a kuku yo shaa ni.

Eyin, e sha ti maje ki a she ole, e je ka tera mo ise wa. Ka gba wipe Oba oke koni gbagbe wa. Ibi ori maa de, ese oni sha lai de be. Akunleyan ti duro.

Aimoye eniyan ti awon omo adarihurun ti fi oju pare. Won ti ro won pin, won ti lero wipe won o le da nkankan mo ni ile aiye yi. Won ti gbagbe wipe awon koni eledumare to she eda onitohun. Nigbati Oba oke ba gbe ishe re de, a de da iru awon eniyan be lare.

Ohun ni anu eni to ba hun fi eda egbe she yeye she maa hun she mi. O maa hun she mi ni kayeefi wipe, eni ti ko mo ola le ma wu iru iwa bayi.

IMG_0431.JPG

Eyin e je ka sha ma she daada. Bi inu wa bati mo ota o le fi wa she nkankan. Bi awa muslims se ma hun so…

Ewe kan o le jabo lara igi lai si ase Oluwa ni ibe.

Nitori na ma she wo nkan ti awon abinu eni hun she. akosile ti duro. Ibi ori maa de, ese oni sha lai de be. Won o le da ise Oluwa duro laelae.

Mo dupe gan fun asiko ti e fisile lati ka aroye mi. E jowo e je kin gbo ero okan yin lori oro yi ni aiye towa ni isale. E dakun e fi ife han mi, Eba mi pin aroye yin fun awon ore yin. Esi ma gbagbe lati darapo mowa ni ibiyi.

Emi ni ti re ni tooto,

Ruka

Check Natural Skincare Products here. Homemade Recipes here.

About Post Author

Ruka

My name is Ruka. Born and bred in Nigeria. Now living in Ireland. I am a Woman, Feminist, Wife, Mother, Muslim, Black, and African. I am an Entrepreneur who also works in Finance Administration. I am a Fibromyalgia & Chronic Pain Warrior. I love writing and hope to make a name for myself doing it.
Happy
Happy
0 %
Sad
Sad
0 %
Excited
Excited
0 %
Sleepy
Sleepy
0 %
Angry
Angry
0 %
Surprise
Surprise
0 %

Average Rating

5 Star
0%
4 Star
0%
3 Star
0%
2 Star
0%
1 Star
0%

Leave a Reply